OJÚ ÌWÉ WẸ́Ẹ̀BÙ GREEK ÌRANRA ẸNI LỌ́WỌ́ ÀKỌ́KỌ́ NÍ FÚN Ẹ̀TỌ́ ỌMỌ ÈNÌYÀN TÍ A ṢE FÚN ÀWỌN OBÌNRIN TÍ A LÒ NÍLÒKULÒ
OWAAT fi ojú ìwé wẹ́ẹ̀bù fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn fún àwọn obìnrin tí a ti lò nílòkulò lọ́lẹ̀ ní Greek láti lè ran ara wọn lọ́wọ́ láti pínyà àti fún ààbò pàjáwìrì.
IṢẸ́ TÍ ẸNI TI FULBRIGHT TI BU ỌLÁ FÚN ṢE LÓRÍ ÀWỌN TÓ FARAGBÁ ÌWÀ IPÁ NÍLÉ NÍ CYPRUS
Ka ìròyìn tí a tẹ̀ jade láti ọwọ́ U.S. Department of State (Gẹ̀ẹ́sì) NIBI
OWAAT LÓ GBA ÒYE TÓ GA JÙ NÍ 2016 FÚN Ẹ̀TỌ́ ỌMỌ ÈNÌYÀN
Àwọn àjọ ABA International Human Rights pẹ̀lú àwọn mìíràn yan OWAAT gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn mẹ́rìndínlógún tí wọ́n jà fún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn jùlọ ní 2016.
Àṣẹ Àkọ́kọ́ Fún Ààbò Ilé Ẹjọ́ Fún Obìnrin Lati Ran Ara Wọn Lọ́wọ́
Ka ìròyìn naa lórí Cyprus Mail NIBI
Ìfọ̀rọ̀-Wá-Ni-Lẹ́nu-Wò Owaat Lórí MyCyRadio
Àwọn onígbọ̀wọ́ Àdúgbò OWAAT mú ọ̀rọ̀ náà jáde lórí MYCYRADIO
Nyoju ohùn Friday 10 April
Gbàgede Àdúgbò Owaat
Àwọn àwòrán láti ọwọ́ àwọn Olùdásílẹ̀ OWAAT Oríṣiríṣi - Ìṣẹ̀lẹ̀ Alátagbà Láàrin àdúgbò àti Iwe Pelebe